ADIITU LAYE lati owo Bade Ojuade Qnà méji ni ìwé yìí pín sí, ònà kin-ín-ní fi í yé wa pé nňkan èşù ni o máa ń wù wá jù. Nínú iwé yií, obìnrin dúró gégé þí êşù léyin ọmọ êniyân, bệệ ni bí ọkùnrin kò bá tíi ní obìnrin nílé,…
Eko Wenjele by Ademola Olayiwola NÍPA ÌWÉ YÌÍ Qmo oko ni Idòwú àti Mórìn i şe. Oko la bí wọn sí; oko la ti wò wọn dàgbà; oko náa ni wọn ti jáde ìwé méwaá. Şugbón nígbà tí èsì ìdánwò àbájáde ò fara rọ, wọn gbàgbó pé Ekó lowo wà.…