TAA LODARAN (Ebook)
₦1,100.00
Taa lodaran lati owo BADE OJUADE
NÍPA ÌWÉ YÌÍ
Eni tó bá ka ìwé xìí ó yę kó ti ka ìwe “Işé Èşù”, ęni tí kò bá sìí tín ka ìwé “Işé Èşù” bó bá ti ka “Taa L’òdaràn” tán, kó yára wá ìwée “Işé Èşù lọ. Bánjí kò so pé Tóórera kò wu òun mó. Awéléwà Títílolá ló fàá. Akínkúnmi là bá sọ pé ó fi ònà kan tó dá wàhálà sílè han Bánjí àti Folájìnmí. Eyin ènìyàn, béè bá sáà tíi ka ìwé yìítán ìbéèrè Onkowé ni pé, Taa L’òdaràn?
Reviews
There are no reviews yet.