TAA LODARAN (Ebook)
₦1,100.00
Taa lodaran lati owo BADE OJUADE
NÍPA ÌWÉ YÌÍ
Eni tó bá ka ìwé xìí ó yę kó ti ka ìwe “Işé Èşù”, ęni tí kò bá sìí tín ka ìwé “Işé Èşù” bó bá ti ka “Taa L’òdaràn” tán, kó yára wá ìwée “Işé Èşù lọ. Bánjí kò so pé Tóórera kò wu òun mó. Awéléwà Títílolá ló fàá. Akínkúnmi là bá sọ pé ó fi ònà kan tó dá wàhálà sílè han Bánjí àti Folájìnmí. Eyin ènìyàn, béè bá sáà tíi ka ìwé yìítán ìbéèrè Onkowé ni pé, Taa L’òdaràn?
Description

NÍPA ONKOWÉ
Bádé Ojúadé ti di òdú nílè kóòtú oòjíire, ó ti kúrò ní àìmò fólóko. Onkowé àti pèdèpèdè lóríi Rédíò àti Móhùnmáwòrán, òun ló kọ ìwée “Işé Eşù”. Eni tó sún mó àgbà ni, tí àwọn àgbà sì fi ęwà èdè àtàșà ró o. Omi n bẹ lámù fún Bádé Ojúadé lóríi ìwé kíko. KÉdùwà òkè jé kó pé láyé, kó le baà şàfihàn àdììtú, tílé ayé jé han àwọn ọmọ Yorùbá, gégé bí Elédùmarè şe fi rán an.
Reviews
There are no reviews yet.