ABIAMO (E BOOK)(E-Book)
₦245.00
Rasmed Publications
Description
Abiamo
Abikú da Titilayo laamú gan-an. Ojú re ri màbo lộdò àwon adähunse ati àwon baba yemiwö. Durógbayê nikan soso ló dúrô nínú ọmo mộkanla ti ó bi. Ohun tí oju Titilayò ri kí Dúrógbayé náa tó dúró ko kéré. Bi Dúrógbayé ti pé omọ odún méwá ni babá rè ti jáde láyé.
Titlayo nikan lỏ n dá bukátà omọ rè gbé láti igbà náa. Titilayp gira tộ Dúrogbayé ti ó fì kẹkọo gboye ni Yunifäsiti ni. Sé Dúrógbayê dúró sanjó fún tyá rệ? Njẹ Titllayo nàa jeun ọmọ kí ó tó re ibi àgbá rè?
Additional information
Weight | 0.0000 kg |
---|---|
Dimensions | 0.00 × 0.00 × 0.00 cm |
Reviews
There are no reviews yet.