EKO WENJELE (ebook)
₦1,000.00
Eko Wenjele by Ademola Olayiwola
NÍPA ÌWÉ YÌÍ
Qmo oko ni Idòwú àti Mórìn i şe. Oko la bí wọn sí; oko la ti wò wọn dàgbà; oko náa ni wọn ti jáde ìwé méwaá. Şugbón nígbà tí èsì ìdánwò àbájáde ò fara rọ, wọn gbàgbó pé Ekó lowo wà. Irìn-àjò níluú Èkó ò dán mórán láti ojó tí wọn ti wọ ìlú nâa. Léyìn odún bíi męta, wọn ò bá ohun tí wón í lé. Kakà béę, láti inú işoro kan ni wọn ti í bó sínú òmíràn. Lójó tí ikú ré bété lóríi wọn ni wón rò ó páá-pàa-pá pé bí iwájú ò bá șe í lọ, şebí èyín ó şe i padà sí, gbogbo ará oko, too, ę kú ojúlónà àwọn ọmọ yín tó şáko règboro Ekó o… Wón ti féré dé!
Description

NÍPA ONKOWÉ
Adémólá Qláyíwolá kàwé gboyè nínú ìmò èdá-èdè àti ède Yorubá (Linquistics/Yoruba) ní Fáfitì Ibadan, léyìn odún méjì gbáko nílé ìwé Polí, Ìbàdàn, ìlú abínibí rè. Irírí rè níagbegbe Ilé-Ifè tó gbé dàgbà ló şokùnfa orúkọ awọn ìleto àti ìlú tó lò nínú ìwé yìí, ní èyí tí ó mú ìtàn inú rè bá işèlè ojú ayé mu. Şugbón ní gàsíkíyá, àròsọ gbáà ni látòkè délè.
Ní nnkan bíi ogójì odún séyìn ni a bí Onkowé yìí níabúlédilú kan tó ń ję Garage-Olódę. O bèrè ìtàn kíkọ pèlú ìwé yìí ní bíi ogún odún séyìn. Àmó kí ó tó gúnlę lórí Èkó Wenjelè Ó ti şaşeyorí lórí àwọn ìwé onítàn bíi méęędógbòn míràn. Ekó Wenjèlè náà nì yí o, ọmọ aráyé ę bá a téwó gba á, nítorí orin tí Eļúkú bá dá lomo rè í gbè.
Reviews
There are no reviews yet.