Adiitu Laye (Ebook)
₦900.00
ADIITU LAYE lati owo Bade Ojuade
Qnà méji ni ìwé yìí pín sí, ònà kin-ín-ní fi í yé wa pé nňkan èşù ni o máa ń wù wá jù. Nínú iwé yií, obìnrin dúró gégé þí êşù léyin ọmọ êniyân, bệệ ni bí ọkùnrin kò bá tíi ní obìnrin nílé, kò tíi gbádùn.
Önà keji ni pè gbogbo ędá pátá, a kân ń wo ara wa gégé bí ęléran ara ni, a kò mọ irú èniyàn tí ęniköökan ję ati pé ohun ti ojú ọmọ ědá miíràn ti ri kò şe é fi ęnu so.
Ę máşe fi ojú lásán wo ęranko tí ń bę ní agbègbè yín, ọmọ ědá miíràn ni wón.
Description
ADIITU LAYE lati owo Bade Ojuade
Nípa ìwé Yií
Qnà méji ni ìwé yìí pín sí, ònà kin-ín-ní fi í yé wa pé nňkan èşù ni o máa ń wù wá jù. Nínú iwé yií, obìnrin dúró gégé þí êşù léyin ọmọ êniyân, bệệ ni bí ọkùnrin kò bá tíi ní obìnrin nílé, kò tíi gbádùn.
Önà keji ni pè gbogbo ędá pátá, a kân ń wo ara wa gégé bí ęléran ara ni, a kò mọ irú èniyàn tí ęniköökan ję ati pé ohun ti ojú ọmọ ědá miíràn ti ri kò şe é fi ęnu so.
Ę máşe fi ojú lásán wo ęranko tí ń bę ní agbègbè yín, ọmọ ědá miíràn ni wón.
Nípa Onkowé
A bí Bádé Ojúadé ní ilú Îfętędó ni ijoba ibílę Gúúsù Ifę ni ipínlę Osun. Ở bệrę ękó aláakóbęrę ni A.U.D Îfętędó, şùgbón ilé ěký aláȧkýběrę L.A. Primary School, Onígbòdògí-Ifę ló ti parí ękó alákýýběrę náà. Ó lọ sí El-Adolabiyah College ilú Qwò, Ipinlę Oşun ní odún 1973 kó tóó gba ilé ęký Ôndó Boys High School, Ondó lo
Ó kékỳó gboyè N.C.E. ní College of Education Îlá-Qràngún, İpínlę Qşun kó tóó korí sí Yunífásíti ti Adó Èkiti níbi tó ti gboyè Akókó lórí imò èdèe Yorùbá. Yunífásíti ilú Ìbàdàn (University of Ibadan) ló ti gba imò ijinlę keji lórí èdè Yorùbá.
Ögbóntarigi önkowé tó ti kọ ìwé Litiréşò lórişiirişii, iwė gírámà, ìwé ewi alohùn àti bệệ bệệ lọ. Pèdèpèdè lórí èro Rédíò àti Móhùnmáwòrán ni Bádé, afèyòsòrò, olórin, öşèré ori itagé. Bádé ti şe fiimú lórişiirişii, olùký ni ilé ęký kékeré àti ilé ękỳ giga ni Bádé Ojúadé, Oníjó ni Bádé, akéwi ni Bádé, ó bímọ, ó sì níyàwó
Reviews
There are no reviews yet.